Ojumo ti mo
Ojumo ti mo mi, nile yi
Ojumo ti mo, mo rire o
Ojumo ti mo
Ojumo ti mo mi, nile yi o
Ojumo ti mo, mo rire o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
Ojumo ti mo
Ojumo ti mo mi, nile yi o
Ojumo ti mo, mo rire o
Ojumo ti mo
Ojumo ti mo mi, nile yi o
Ojumo ti mo, mo rire o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
[Ha] Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
[Ha, eei k ngbo se] Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
[Flute plays]
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi, ojumo ti mo, mo ri re o
Oh oh oh oh oh oh...mo ri're o
Oh oh oh oh oh oh ...mo ri're o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi o, ojumo ti mo, mo ri re o
Eiye adaba, eiye adaba ti n foloke loke
Wa balemi o, ojumo ti mo, mo ri re o
Note: All song lyrics are the property and copyright of their original owners and authors.
No comments:
Post a Comment